Ìjọba Tinubu yíì kì í bá ẹgbẹ òṣìṣẹ́ sọ àsọyépọ̀- Joe Ajaero, Ààrẹ NLC - BBC News Yorùbá
Aarẹ ẹgbẹ awọn oṣiṣẹ Naijiria; "Nigeria Labour Congress" (NLC), Joe Ajaero, ti fẹsun kan ijọba Aarẹ Bola Tinubu, pe wọn ki i ba ẹgbẹ naa sọ aṣoyepọ bo ṣe yẹ.
BBC News Yoruba1 个来源阅读 1 分钟归档于2026年10月4日
