跳到正文
FeedAtom
登录

BBC News Yoruba

BBC News Yoruba报道的每条新闻,按来源相互佐证的程度排序。

访问BBC News Yoruba

这是通用信息流,没有按你的偏好调整。 登录以定制你的信息流

Makinde ní ipò Gómìnà ìpínlẹ̀ Oyo kọjá ọ̀rọ̀ Kọ́kọ́rọ́ Alátẹ, Oriyomi náà dá a padà - BBC News Yorùbá

Makinde lo kọkọ sọ pe didupo gomina ipinlẹ Oyo kii ṣe ọrọ awada, o si kọja ọrọ Kọkọrọ Alatẹ, iyẹn eto kan ti Oriyomi maa n ṣe lori redio Agidigbo FM n'Ibadan.

BBC News Yoruba2 个来源阅读 1 分钟

I didn’t know Ogogo was battling health issues – Peter Fatomilola

Veteran Yoruba actor, Peter Fatomilola, has said he was unaware that fellow actor, Taiwo Hassan, popularly known as Ogogo, was battling health challenges before the actor’s daughter made the situation public.

Punch2 个来源阅读 1 分钟

Wo àwọn ilẹ̀ àti dúkìá tí ìjọba àpapọ̀ ṣèkìlọ̀ pé ẹnikẹ́ni kò gbọdọ̀ rà ní ìpínlẹ̀ Oyo - BBC News Yorùbá

Ijọba apapọ ti ṣekilọ fawọn olugbe ipinlẹ Oyo ati agbegbe lati ṣe iwadii ki wọn to ra ilẹ tawọn kan n polongo rẹ ni ipinlẹ naa lẹnu ọjọ mẹta yii.

BBC News Yoruba2 个来源阅读 1 分钟

Ta ni Omowunmi Dada, gbajúmọ̀ òṣèré tí sinimá òun àti Lateef Adedimeji, Itele D Icon, gba àmì ẹ̀yẹ GWR? - BBC News Yorùbá

Omowunmi Dada wa lara awọn olootu to ṣe agbatẹru fiimu, Black Market pẹlu ajọṣepọ Fatimah Binta Gimsay ati Abdul Tijani-Ahmed lati fi gba ami ẹyẹ Guinness World Record lori fiimu ti ero pọ si julọ nibẹ lati wo o ni oju kan ṣoṣo.

BBC News Yoruba1 个来源阅读 1 分钟

Ṣé lóòótọ́ ni Ààrẹ Naijiria lè máa ṣèjọba láti ilẹ̀ òkèrè? - BBC News Yorùbá

Ijọba apapọ ti sọ pe aarin ọsẹ yii ni Aarẹ Bola Tinubu yoo pada si Naijiria lẹyin to ti kọkọ lọ sinmi loke okun fun nnkan bii ọjọ mọkanlelogun.

BBC News Yoruba1 个来源阅读 1 分钟

Níbo Layé Kọjú Sí: Ọmọbìnrin máa ń láàánú lójú ju ọkùnrin lọ – Olori Sekinat Elegushi - BBC News Yorùbá

Níbo Layé Kọjú Sí: Ọmọbìnrin máa ń láàánú lójú ju ọkùnrin lọ – Olori Sekinat Elegushi

BBC News Yoruba1 个来源阅读 1 分钟

Wo àwọn iṣẹ́ tí ìjọba UK gbé jáde táwọn èèyàn fi lè wọ orílẹ̀ èdè náà - BBC News Yorùbá

Ijọba United Kingdom, UK ti kede awọn iṣẹ ti awọn eeyan ilẹ okeere fi le fi wọ orilẹ ede naa labẹ eto awọn ti wọn le gba ilana iṣẹ ṣiṣe wọbẹ.

BBC News Yoruba1 个来源阅读 1 分钟

Wo ọ̀nà márùn-ún tí o lé gbà dènà ibà ọ̀rẹ̀rẹ̀ (Lassa Fever) tó ti ṣekúpa èèyàn 259 báyìí - BBC News Yorùbá

Ajọ NCDC to n gbogun ti ajakalẹ arun ni Naijiria ti sọ pe iba ọrẹrẹ ti ọpọ mọ si lassa fever ti ṣekupa eeyan 259 lọdun 2026 yii.

BBC News Yoruba1 个来源阅读 1 分钟

    Cookie

    我们不用 Cookie 统计访问。会设置 Cookie 的分析工具,只在您允许后才运行。