Wo àwọn iṣẹ́ tí ìjọba UK gbé jáde táwọn èèyàn fi lè wọ orílẹ̀ èdè náà - BBC News Yorùbá
Ijọba United Kingdom, UK ti kede awọn iṣẹ ti awọn eeyan ilẹ okeere fi le fi wọ orilẹ ede naa labẹ eto awọn ti wọn le gba ilana iṣẹ ṣiṣe wọbẹ.
BBC News Yoruba1 个来源阅读 1 分钟归档于2026年9月26日
