Ṣé lóòótọ́ ni Ààrẹ Naijiria lè máa ṣèjọba láti ilẹ̀ òkèrè? - BBC News Yorùbá
Ijọba apapọ ti sọ pe aarin ọsẹ yii ni Aarẹ Bola Tinubu yoo pada si Naijiria lẹyin to ti kọkọ lọ sinmi loke okun fun nnkan bii ọjọ mọkanlelogun.
BBC News Yoruba1 个来源阅读 1 分钟归档于2026年9月28日
