Ipa tí ẹgbẹ̀lẹ́gbẹ̀ mílíọ̀nù lítà bẹntiróòlù tíjọba ní káwọn alágbàtà epo mẹ́fà kó wọlé yóò ní lórí ọmọ Naijiria - BBC News Yorùbá
Amọ, Dangote duro lori ẹsẹ rẹ pe ileeṣẹ ifọpo oun lagbara lati pese epo ti gbogbo ọmọ Naijiria nilo.
BBC News Yoruba1 个来源阅读 1 分钟归档于2026年9月24日
