Skip to content
FeedAtom

BBC News Yoruba

Every story BBC News Yoruba reported, ranked by how well its sources corroborate it.

Visit BBC News Yoruba

This is the general feed. It is not shaped to you. Sign in to shape it

Chinda Ogundu: Wetin Supreme Court judgement on electoral act mean Rivers APC Govnorship candidate and odas? - BBC News Pidgin

Concerns dey about di candidacy of di All Progressives Govnorship candidate for Rivers State, Ogundu Kingsley Chinda sake of di Supreme Court judgement wey restore some provisions of di Electoral Act 2026.

BBC News Pidgin3 sources1 min read

Ta ni Omowunmi Dada, gbajúmọ̀ òṣèré tí sinimá òun àti Lateef Adedimeji, Itele D Icon, gba àmì ẹ̀yẹ GWR? - BBC News Yorùbá

Omowunmi Dada wa lara awọn olootu to ṣe agbatẹru fiimu, Black Market pẹlu ajọṣepọ Fatimah Binta Gimsay ati Abdul Tijani-Ahmed lati fi gba ami ẹyẹ Guinness World Record lori fiimu ti ero pọ si julọ nibẹ lati wo o ni oju kan ṣoṣo.

BBC News Yoruba2 sources1 min read

Tí a bá ṣe afiwé pẹ̀lú àwọn orílẹ̀èdè tó yíi ká, owó epo bẹntirólù Nàìjíríà ló kéré jùlọ – Dangote - BBC News Yorùbá

Aliko Dangote, baba olowo to ni ileeṣẹ ifọpo Dangote ti sọrọ sita pe irọ lawọn to n pariwo pe idasilẹ ileeṣẹ epo Dangote ko mu irọrun ba owo ti awọn eeyan n san lori epo bẹntiro lorilẹede Naijiria, ati wi pe dipo bẹẹ nṣe lo n peleke sii.

BBC News Yoruba1 source1 min read

Wo kókó àbájáde ìwádìí ìjóba Oyo lórí ìjínigbé Oriire - BBC News Yorùbá

Igbimọ to ṣewadii ijinigbe to waye ni ijọba ibilẹ Oriire, nipinlẹ Oyo ti gbe abajade iwadii rẹ jade, o si ti fi le gomina Seyi Makinde lọwọ.

BBC News Yoruba1 source1 min read

Makinde ní ipò Gómìnà ìpínlẹ̀ Oyo kọjá ọ̀rọ̀ Kọ́kọ́rọ́ Alátẹ, Oriyomi náà dá a padà - BBC News Yorùbá

Makinde lo kọkọ sọ pe didupo gomina ipinlẹ Oyo kii ṣe ọrọ awada, o si kọja ọrọ Kọkọrọ Alatẹ, iyẹn eto kan ti Oriyomi maa n ṣe lori redio Agidigbo FM n'Ibadan.

BBC News Yoruba2 sources1 min read

    Cookies

    We count visits without cookies. Analytics tools that do set cookies only run if you allow them.