Ẹ̀dínwó epo bẹntiróòlù tuntun: Tani yóò san án? Tani yóò jẹ anfani rẹ? - BBC News Yorùbá
Ni ipinlẹ Ọṣun ile epo NNPC to wa lagbegbe Abeere ni ilu Osogbo n ta epo naa ni ẹgbẹrun kan o le ọọdunrun ati mejilelogun Naira (N1322) bi o tilẹ je pe oju itepo kan ninu oju itepo ogun to wa nile itepo naa ni wọn ti n ta epo.
BBC News Yoruba3 sources1 min readFiled October 10, 2026
