Lẹ́yìn ọ̀pọ̀lọpọ̀ wàhálà, gbajúmọ̀ akọ̀ròyìn yóò di ọba alayé ní Uganda - BBC News Yorùbá
O ṣiṣẹ gẹgẹ bi agbohunsafẹfẹ fun ogun ọdun le diẹ, to si ṣiṣẹ kaakiri lawọn orileede bii Rwanda ko to tun pada si ileeṣẹ igbohunsafẹfẹ orileede Uganda, iyẹn UBC.
BBC News Yoruba1 source1 min readFiled September 29, 2026
