Ohun tó fa ìjà tí ayé ń pariwo láàrin èmi àti Ogogo rèé àti bí a ṣe yanjú rẹ̀ - Yinka Quadri - BBC News Yorùbá
Agbaọjẹ osẹre tiata Yoruba n ni, Yinka Quadri, ti ọpọ eeyan mọ si Kura ti tan imọlẹ si ede-ai-yede to waye laarin rẹ ati ọrẹ Taiwo Hassan to doloogbe.
BBC News Yoruba2 sources1 min readFiled October 7, 2026
